Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Manners: Rules for guests 2 ẹsẹ · 3 abala Wá "Manners" Gbogbo 2 Rules for guests 2 Courteousness enjoined · Obeisance to strangers · Àwọn ẹsẹ nípa Rules for guests Òwe 23:1Nígbà tí ìwọ bá jókòó láti bá ìjòyè jẹun, kíyèsi ohun tí ó wà níwájú rẹ gidigidi.Òwe 23:2Ìwọ a sì fi ọ̀bẹ lé ara rẹ ní ọ̀fun, bí ìwọ bá jẹ́ òkúndùn ènìyàn.