Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Machir: 2. A man of Lo-Debar who took care of Jonathan's lame son, Mephibosheth

2 ẹsẹ · 1 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 2. A man of Lo-Debar who took care of Jonathan's lame son, Mephibosheth

  1. Ọba sì wí fún un pé, “Níbo ni ó gbé wà?” Ṣiba sì wí fún ọba pé, “Wò ó, òun wà ní ilé Makiri, ọmọ Ammieli, ní Lo-Debari.”

  2. Dafidi ọba sì ránṣẹ́, ó sì mú un láti ilé Makiri ọmọ Ammieli láti Lo-Debari wá.