Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Lo-Debar: A city in Manasseh

2 ẹsẹ · 2 abala

Àwọn ẹsẹ nípa A city in Manasseh

  1. Ọba sì wí fún un pé, “Níbo ni ó gbé wà?” Ṣiba sì wí fún ọba pé, “Wò ó, òun wà ní ilé Makiri, ọmọ Ammieli, ní Lo-Debari.”

  2. Dafidi ọba sì ránṣẹ́, ó sì mú un láti ilé Makiri ọmọ Ammieli láti Lo-Debari wá.