Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Lion: Twelve statues of, on the stairs leading to Solomon's throne

2 ẹsẹ · 16 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Twelve statues of, on the stairs leading to Solomon's throne

  1. Ìtẹ́ náà sì ní àtẹ̀gùn mẹ́fà, ẹ̀yìn rẹ̀ sì ṣe róbótó lókè. Ní ibi ìjókòó méjèèjì náà ni ìrọpá wà, pẹ̀lú kìnnìún tí ó dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn.

  2. Kìnnìún méjìlá sì dúró níbi àtẹ̀gùn mẹ́fẹ̀ẹ̀fà, ọ̀kọ̀ọ̀kan ní òpin àtẹ̀gùn kọ̀ọ̀kan, kò tí ì sí irú rẹ̀ ní ìjọba kan rí.