Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Laadan: 2. A Levite, called Libni
Àwọn ẹsẹ nípa 2. A Levite, called Libni
Àwọn tí ó jẹ́ ọmọ Gerṣoni: Laadani àti Ṣimei.
Àwọn ọmọ Laadani Jehieli ẹni àkọ́kọ́, Setamu àti Joẹli, mẹ́ta ní gbogbo wọn.
Àwọn ọmọ Ṣimei: Ṣelomiti, Hasieli àti Harani mẹ́ta ní gbogbo wọn. Àwọn wọ̀nyí sì ni olórí àwọn ìdílé Laadani.