Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Joseph: 9. Called Barsabas, surnamed Justus. One of the two persons nominated in place of Judas

3 ẹsẹ · 8 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 9. Called Barsabas, surnamed Justus. One of the two persons nominated in place of Judas

  1. Nítorí náà, ó di dandan láti yan ọ̀kan nínú àwọn ọkùnrin wọ̀nyí ti ń bá wa rìn ni gbogbo àkókò tí Jesu Olúwa ń wọlé, tí ó sì jáde láàrín wa.

  2. Bẹ́ẹ̀ láti ìgbà bamitiisi Johanu títí ó fi di ọjọ́ náà ti a gbe é lọ sókè kúrò lọ́dọ̀ wa. Ó yẹ kí ọ̀kan nínú àwọn wọ̀nyí ṣe ẹlẹ́rìí àjíǹde rẹ̀ pẹ̀lú wa.”

  3. Wọn sì yan àwọn méjì, Josẹfu tí a ń pè ní Barsaba (ẹni tí a sọ àpèlé rẹ̀ ni Justu) àti Mattia.