Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Jezreel 2 ẹsẹ · 4 abala Wá "Jezreel" Gbogbo 2 5. Figurative of Israel 2 1. A city in southern Judah · 3. A valley · 4. A descendant of Etam · Àwọn ẹsẹ Bíbélì pàtàkì Hosea 1:4Nígbà náà ni Olúwa sọ fún Hosea pé, “Pe orúkọ ọmọ náà ní Jesreeli, nítorí pé láìpẹ́ ni èmi yóò jẹ ìdílé Jehu ní ìyà fún ẹ̀jẹ̀ àwọn ènìyàn tó pa ní ìpakúpa ní Jesreeli, Èmi yóò sì mú ìjọba Israẹli wá sí òpin.Hosea 1:5Ní ọjọ́ náà ni Èmi yóò ṣẹ́ ọrun Israẹli ní àfonífojì Jesreeli.”