Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa History: General references 3 ẹsẹ · 1 abala Wá "History" Gbogbo 3 General references 3 Àwọn ẹsẹ nípa General references Jobu 8:8“Èmi bẹ̀ ọ́ ǹjẹ́, béèrè lọ́wọ́ àwọn ará ìgbà nì kí o sì kíyèsi ìwádìí àwọn baba wọn.Jobu 8:9Nítorí pé ọmọ-àná ni àwa, a kò sì mọ nǹkan, nítorí pé òjìji ni ọjọ́ wa ni ayé.Jobu 8:10Àwọn kì yóò wa kọ ọ́, wọn kì yóò sì sọ fún ọ? Wọn kì yóò sì sọ̀rọ̀ láti inú òye wọn jáde wá?