Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Hilkiah: 2. High priest

2 ẹsẹ · 4 abala

Wá "Hilkiah"

Àwọn ẹsẹ nípa 2. High priest

  1. Nígbà tí wọ́n mú owó náà tí wọ́n mú wá sí ilé Olúwa, Hilkiah àlùfáà sì rí ìwé òfin Olúwa tí a ti fi fún un láti ọwọ́ Mose.

  2. Hilkiah sì wí fún Ṣafani akọ̀wé pé, “Èmi ti rí ìwé òfin nínú ilé Olúwa.” Ó sì fi fún Ṣafani.