Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Galeed: Called also Jegar-Sahadutha, the memorial of Jacob's and Laban's covenant.
Àwọn ẹsẹ nípa Called also Jegar-Sahadutha, the memorial of Jacob's and Laban's covenant.
Labani sì pe orúkọ rẹ̀ ní Jegari-Sahaduta, ṣùgbọ́n Jakọbu pè é ni Galeedi.
Labani sì wí pé, “Òkìtì yìí jẹ́ ẹ̀rí láàrín èmi àti ìwọ ní òní.” Ìdí nìyí tí a fi pe orúkọ rẹ̀ ni Galeedi.