Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Galatia

2 ẹsẹ · 4 abala

Àwọn ẹsẹ Bíbélì pàtàkì

  1. Paulu, aposteli tí a rán kì í ṣe láti ọ̀dọ̀ ènìyàn wá, tàbí nípa ènìyàn, ṣùgbọ́n nípa Jesu Kristi àti Ọlọ́run Baba, ẹni tí ó jí i dìde kúrò nínú òkú.

  2. Àti gbogbo àwọn arákùnrin tí ó wà pẹ̀lú mi, Sí àwọn ìjọ ní Galatia: