Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Evil for Good 2 ẹsẹ · 1 abala Wá "Evil for Good" Gbogbo 2 General references 2 Àwọn ẹsẹ Bíbélì pàtàkì Saamu 7:4bí èmi bá ṣe ibi sí ẹni tí ń wá àlàáfíà pẹ̀lú mi, tí mo ja ọ̀tá mi lólè láìnídìí,Saamu 7:5nígbà náà, jẹ́ kí ọ̀tá mi lé mi kí wọn sì mú mi; jẹ́ kí òun kí ó tẹ ọkàn mi mọ́lẹ̀ kí wọn sì mú mi sùn nínú eruku. Sela.