Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Enoch: 1. Eldest son of Cain

2 ẹsẹ · 2 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 1. Eldest son of Cain

  1. Kaini sì bá aya rẹ̀ lòpọ̀, ó sì lóyún, ó sì bí Enoku. Kaini sì tẹ ìlú kan dó, ó sì fi orúkọ ọmọ rẹ̀ ọkùnrin Enoku sọ ìlú náà.

  2. Enoku sì bí Iradi, Iradi sì ni baba Mehujaeli, Mehujaeli sì bí Metuṣaeli, Metuṣaeli sì ni baba Lameki.