Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Discipline of the Church: Exercise, in a spirit of charity

3 ẹsẹ · 10 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Exercise, in a spirit of charity

  1. Ìyà náà tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ti fi jẹ́ irú ènìyàn bẹ́ẹ̀ tó fún un.

  2. Kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ̀yin ìbá kúkú dáríjì í, kí ẹ sí tù ú nínú ní gbogbo ọ̀nà, kí ìbànújẹ́ má bà á bo irú ènìyàn bẹ́ẹ̀ mọ́lẹ̀.

  3. Nítorí náà mo bẹ̀ yín, ẹ fi ìdánilójú ìfẹ́ yín hàn sí irú ẹni náà.