Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Carnal Mindedness: General references 3 ẹsẹ · 1 abala Wá "Carnal Mindedness" Gbogbo 3 General references 3 Àwọn ẹsẹ nípa General references Romu 8:6Nítorí èrò ti ara ikú ni; ṣùgbọ́n èrò ti ẹ̀mí ni ìyè àti àlàáfíà.Romu 8:7Nítorí èrò ti ara ọ̀tá ni sí Ọlọ́run, nítorí kì í tẹríba fún òfin Ọlọ́run, òun kò tilẹ̀ le ṣe e.Romu 8:8Ìdí nìyìí tí àwọn tí ó wà lábẹ́ àkóso ara ẹ̀ṣẹ̀, kò le è tẹ́ Ọlọ́run lọ́rùn.