Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Bottle 2 ẹsẹ · 4 abala Wá "Bottle" Gbogbo 2 Made of skins 2 General references · Made of clay · Used as a lachrymatory · Àwọn ẹsẹ Bíbélì pàtàkì Luku 5:37Àti wí pé, kò sí ẹni tí ó lè dá ọtí wáìnì tuntun sínú ògbólógbòó ìgò-awọ, tí ó bá ṣe èyí, wáìnì tuntun yóò fa awọ náà ya, wáìnì náà yóò dànù, awọ náà a sì bàjẹ́.Luku 5:38Nítorí náà, ó tọ́ kí á da wáìnì tuntun sínú awọ tuntun.