Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Beriah: 1. Son of Asher

2 ẹsẹ · 4 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 1. Son of Asher

  1. Ti àwọn ọmọ Aṣeri gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: ti Imina, ìdílé àwọn ọmọ Imina; ti Iṣfi, ìdílé àwọn ọmọ Iṣfi; ti Beriah, ìdílé àwọn ọmọ Berii.

  2. Ti àwọn ọmọ Beriah: ti Heberi, ìdílé àwọn ọmọ Heberi; ti Malkieli, ìdílé àwọn ọmọ Malkieli.