Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Bed

3 ẹsẹ · 8 abala

Àwọn ẹsẹ Bíbélì pàtàkì

  1. Wò ó! Àkéte rẹ̀ tí í ṣe ti Solomoni, àwọn akọni ọgọ́ta ni ó wà yí i ká, àwọn akọni Israẹli,

  2. gbogbo wọn ni ó mú idà lọ́wọ́, gbogbo wọn ní ìmọ̀ nínú ogun, idà oníkálùkù wà ní ẹ̀gbẹ́ rẹ̀, wọ́n múra sílẹ̀ fún ìdágìrì òru

  3. Solomoni ọba ṣe àkéte fún ara rẹ̀; o fi igi Lebanoni ṣe é.