Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Aquila and Priscilla: Friendship of, for Paul 2 ẹsẹ · 3 abala Wá "Aquila and Priscilla" Gbogbo 7 Christians at Corinth 5 Friendship of, for Paul 2 Paul sends salutations to · Àwọn ẹsẹ nípa Friendship of, for Paul Romu 16:3Ẹ kí Priskilla àti Akuila, àwọn tí ó ti jẹ́ alábáṣiṣẹ́pọ̀ mi nínú Kristi Jesu.Romu 16:4Àwọn tí wọ́n ti fi ẹ̀mí wọn wéwu nítorí mi. Kì í ṣe èmi nìkan àti gbogbo àwọn ìjọ àwọn aláìkọlà ń dúpẹ́ lọ́wọ́ wọn.