Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Amminadab: 3. A son of Uzziel

2 ẹsẹ · 2 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 3. A son of Uzziel

  1. Méjìléláàádọ́fà nínú àwọn ọmọ Usieli; Amminadabu olórí àti àwọn ẹbí rẹ̀.

  2. Dafidi sì ránṣẹ́ pe Sadoku, Abiatari tí wọ́n jẹ́ àlùfáà, àti Urieli, Asaiah. Joẹli, Ṣemaiah, Elieli àti Amminadabu tí wọ́n jẹ́ Lefi.