Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Ahiah: 1. Grandson of Phinehas

2 ẹsẹ · 3 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 1. Grandson of Phinehas

  1. lára wọn ni Ahijah, tí ó wọ efodu. Òun ni ọmọ arákùnrin Ikabodu Ahitubu, ọmọ Finehasi, ọmọ Eli, àlùfáà Olúwa ní Ṣilo kò sí ẹni tí ó mọ̀ pé Jonatani ti lọ.

  2. Saulu sì wí fún Ahijah pé, “Gbé àpótí Ọlọ́run wá.” Àpótí Ọlọ́run wà pẹ̀lú àwọn ọmọ Israẹli ní ìgbà náà.