Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Agate: A precious stone.

3 ẹsẹ · 1 abala

Àwọn ẹsẹ nípa A precious stone.

  1. ní ẹsẹ̀ kẹta, jasiniti, agate, àti ametisiti;

  2. Èmi yóò fi iyùn ṣe odi rẹ, àwọn ẹnu-ọ̀nà ni a ó fi ohun èlò dáradára fún, àti àwọn ògiri rẹ pẹ̀lú òkúta iyebíye.

  3. “ ‘Aramu ṣòwò pẹ̀lú nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ òwò rẹ̀; wọn ṣe ìpààrọ̀ òkúta iyebíye, òwú elése àlùkò, aṣọ iṣẹ́ ọnà abẹ́rẹ́, aṣọ ọ̀gbọ̀ dáradára, ìlẹ̀kẹ̀ iyùn pupa fún ọjà títà rẹ.