Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Achbor: 1. Father of King Baal-Hanan

2 ẹsẹ · 3 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 1. Father of King Baal-Hanan

  1. Nígbà tí Baali-Hanani ọmọ Akbori kú, Hadadi ni ó jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Orúkọ ìlú rẹ̀ ni Pau, orúkọ ìyàwó sì ni Mehetabeeli ọmọbìnrin Matiredi, ọmọbìnrin Mesahabu.

  2. Nígbà tí Saulu kú, Baali-Hanani, ọmọ Akbori jẹ ọba ní ipò rẹ̀.