Giloh
31.6100, 35.0800 Wo lórí Google Maps
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Giloh
Goṣeni, Holoni àti Giloni, ìlú mọ́kànlá àti ìletò wọn.
Absalomu sì ránṣẹ́ pe Ahitofeli ará Giloni, ìgbìmọ̀ Dafidi, láti ìlú rẹ̀ wá, àní láti Giloni, nígbà tí ó ń rú ẹbọ. Ìdìmọ̀lù náà sì le; àwọn ènìyàn sì ń pọ̀ sọ́dọ̀ Absalomu.