Fò sí àkóónú

Gennesaret

3 verses

32.8500, 35.5000 Wo lórí Google Maps

Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Gennesaret

  1. Nígbà tí wọn rékọjá sí apá kejì wọ́n gúnlẹ̀ sí Genesareti.

  2. Lẹ́yìn tí wọ́n la Òkun náà kọjá, wọ́n gúnlẹ̀ sí Genesareti. Wọ́n sì so ọkọ̀ sí èbúté.

  3. Ó sì ṣe, nígbà tí ìjọ ènìyàn súnmọ́ ọn láti gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, tí ó sì dúró létí adágún Genesareti.