Aram-maacah
A tún mọ̀ ọ́n sí: Syria-maachah
33.2000, 36.5000 Wo lórí Google Maps
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Aram-maacah
Nígbà tí àwọn ará Ammoni sì ri pé wọ́n ti di ẹ̀ṣẹ̀ ní ihò imú Dafidi, Hanuni àti àwọn ará Ammoni rán ẹgbẹ̀rún (1,000) tálẹ́ǹtì fàdákà láti gba iṣẹ́ àwọn kẹ̀kẹ́ àti àwọn agun-kẹ̀kẹ́ láti Aramu-Naharaimu, Siria Maaka àti Soba.