Luke
A tún mọ̀ ọ́n sí: Lucas
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Luke
Luku, arákùnrin wa ọ̀wọ́n, oníṣègùn, àti Dema ki í yín.
Luku nìkan ni ó wà pẹ̀lú mi, mú Marku wá pẹ̀lú rẹ: nítorí ó wúlò fún mi fún iṣẹ́ ìránṣẹ́.
Marku kí ọ pẹ̀lú Aristarku, Dema àti Luku, àwọn alábáṣiṣẹ́ mi.