Fò sí àkóónú

Jephthah

26 ẹsẹ · 1 ọmọ ẹbí

A tún mọ̀ ọ́n sí: Jephthae

Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Jephthah

Sẹ́ nípa ìwé
  1. Èwo ni èmi o sì tún máa wí sí i? Nítorí pé ìgbà yóò kùnà fún mi láti sọ ti Gideoni, àti Baraki, àti Samsoni, àti Jefta; àti Dafidi, àti Samuẹli, àti ti àwọn wòlíì,