Skip to content

Ithream

2 ẹsẹ · 22 ọmọ ẹbí

Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Ithream

  1. Ẹ̀kẹfà sì ni Itreamu, tí Egla aya Dafidi bí fún un. Wọ̀nyí ni a bí fún Dafidi ni Hebroni.

  2. ẹ̀karùnún ni Ṣefatia láti ọ̀dọ̀ Abitali; àti ẹ̀kẹfà, Itreamu, láti ọ̀dọ̀ Egla aya rẹ̀.