Skip to content

Hatach

4 ẹsẹ

Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Hatach

  1. Nígbà náà ni Esteri pe Hataki, ọ̀kan nínú àwọn ìwẹ̀fà ọba tí a yàn láti máa jíṣẹ́ fún un, ó pàṣẹ fún un pé kí ó béèrè ohun tí ó ń dààmú Mordekai àti ohun tí ó ṣe é.

  2. Bẹ́ẹ̀ ni Hataki jáde lọ bá Mordekai ní ìta gbangba ìlú níwájú ẹnu-ọ̀nà ọba.

  3. Hataki padà ó sì lọ ṣàlàyé fún Esteri ohun tí Mordekai sọ.

  4. Nígbà náà ni Esteri pàṣẹ fún Hataki pé kí ó sọ fún Mordekai,