Skip to content

Adbeel

2 ẹsẹ · 13 ọmọ ẹbí

Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Adbeel

  1. Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Iṣmaeli bí a ṣe bí wọn, bẹ̀rẹ̀ láti orí: Nebaioti àkọ́bí, Kedari, Adbeeli, Mibsamu,

  2. Èyí ni àwọn ọmọ náà: Nebaioti àkọ́bí Iṣmaeli: Kedari, Adbeeli, Mibsamu,