Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Sidonians: All their helpers to be cut off
Àwọn ẹsẹ nípa All their helpers to be cut off
Nítorí tí ọjọ́ náà ti pé láti pa àwọn Filistini run, kí a sì mú àwọn tí ó là tí ó lè ran Tire àti Sidoni lọ́wọ́ kúrò. Olúwa ti ṣetán láti pa Filistini run, àwọn tí ó kù ní agbègbè Kafitori.