Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Oak Tree: Of strong and powerful men
Àwọn ẹsẹ nípa Of strong and powerful men
“Mo pa àwọn ará Amori run níwájú wọn gíga ẹni tí ó dàbí igi kedari. Òun sì le koko bí igi óákù mo pa èso rẹ̀ run láti òkè wá àti egbò rẹ̀ láti ìsàlẹ̀ wá.