Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Seals: Attached to the victims approved for sacrifice, alluded to
Àwọn ẹsẹ nípa Attached to the victims approved for sacrifice, alluded to
Ẹ má ṣe ṣiṣẹ́ fún oúnjẹ tí ń ṣègbé, ṣùgbọ́n fún oúnjẹ tí ó wà títí di ayé àìnípẹ̀kun, èyí tí Ọmọ Ènìyàn yóò fi fún yín. Nítorí pé òun ni, àní Ọlọ́run Baba ti fi èdìdì dì í.”