Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Offerings: Many offences under the law, beyond the efficacy of
Àwọn ẹsẹ nípa Many offences under the law, beyond the efficacy of
Nítorí náà, mo búra sí ilé Eli, ‘Ìwà ẹ̀ṣẹ̀ ilé Eli ni a kì yóò fi ẹbọ tàbí ọrẹ mú kúrò láéláé.’ ”
Nítorí ìwọ kò ní inú dídùn sí ẹbọ, tí èmi kò bá mú wá; Ìwọ kò ní inú dídùn sí ọrẹ ẹbọ sísun.