Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Oaths: Forbidden to take rash, or unholy

1 ẹsẹ · 41 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Forbidden to take rash, or unholy

  1. Tàbí bí ẹni kan bá búra láti ṣe ohun kan láì ronú lé e lórí, yálà ohun tó dára tàbí ohun búburú, nínú ọ̀rọ̀ yówù tó ti búra láì kíyèsi ara, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé, kò mọ̀ nípa rẹ̀ tẹ́lẹ̀, bí ó ti wù kó rí, nígbà tó bá mọ̀ yóò jẹ̀bi.