Skip to content
Òwe 24:21-22

Bẹ̀rù Ọlọ́run kí o sì bọ̀wọ̀ fún ọba

Òwe 24:21-22
21
Bẹ̀rù Olúwa àti ọba, ọmọ mi, má sì ṣe darapọ̀ pẹ̀lú àwọn olórí kunkun.
22
Nítorí àwọn méjèèjì yóò rán ìparun òjijì sórí wọn, ta ni ó sì mọ irú ìyọnu tí wọ́n lè mú wá?
Settings

Reading style

Typeface

Font size 19px

Reading width 90 chars

Options