Fò sí àkóónú
Luku 4:14-15

Jésù bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìránṣẹ́ ní Gálílì

Luku 4:14-15
14
Jesu sì fi agbára Ẹ̀mí padà wá sí Galili, òkìkí rẹ̀ sì kàn kálẹ̀ ní gbogbo agbègbè tí ó yí i ká.
15
Ó sì ń kọ́ni nínú Sinagọgu wọn; a ń yìn ín lógo láti ọ̀dọ̀ gbogbo àwọn ènìyàn wá.
Settings

Reading Style

Typeface

Font Size 19px

Options