Skip to content
Onidajọ 13:1-2

Filistia ń ni Israẹli lára

Onidajọ 13:1-2
1
Àwọn ọmọ Israẹli sì túnṣe ohun tí ó burú ní ojú Olúwa, Olúwa sì fi wọ́n lé àwọn ará Filistini lọ́wọ́ fún ogójì ọdún.
2
Ọkùnrin ará Sora kan wà, orúkọ rẹ̀ a máa jẹ́ Manoa láti ẹ̀yà Dani. Aya rẹ̀ yàgàn kò sì bímọ.
Settings

Reading style

Typeface

Font size 19px

Reading width 90 chars

Options