Fò sí àkóónú
Joṣua 1:10-11

Jóṣúà pàṣẹ fún ìmúrasílẹ̀ láti sọdá

Joṣua 1:10-11
10
Báyìí ni Joṣua pàṣẹ fún olórí àwọn ènìyàn rẹ̀,
11
“Ẹ la ibùdó já, kí ẹ sì sọ fún àwọn ènìyàn, ‘Ẹ pèsè oúnjẹ yín sílẹ̀. Ní ìwòyí ọ̀túnla, ẹ̀yin yóò la Jordani yìí kọjá, láti gba ilẹ̀ tí Olúwa Ọlọ́run yín fi fún un yín láti ní.’ ”
Settings

Reading Style

Typeface

Font Size 19px

Reading Width 45 chars

Options