Skip to content
Ìṣe àwọn Aposteli 3:4-5

Ìṣe àwọn Aposteli 3:4-5

4
Peteru sì tẹjúmọ́ ọn, pẹ̀lú Johanu, ó ní “Wò wá!”
5
Ó sì fiyèsí wọn, ó ń retí láti rí nǹkan láti gbà lọ́wọ́ wọn.
Settings

Reading Style

Typeface

Font Size 19px

Options