Skip to content
Ìṣe àwọn Aposteli 12:24-25

Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ń dàgbà

Ìṣe àwọn Aposteli 12:24-25
24
Ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ Ọlọ́run gbilẹ̀, ó sì bí sí i.
25
Barnaba àti Saulu sì padà wá láti Jerusalẹmu, nígbà ti wọ́n sì parí iṣẹ́ ìránṣẹ́ wọn, wọn sì mú Johanu ẹni tí àpèlé rẹ̀ ń jẹ́ Marku wá pẹ̀lú wọn.
Settings

Reading style

Typeface

Font size 19px

Reading width 90 chars

Options