Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Zerahiah
Àwọn ẹsẹ Bíbélì pàtàkì
Ussi baba Serahiah, Serahiah baba Meraioti,
Bukki ọmọ rẹ̀, Ussi ọmọ rẹ̀, Serahiah ọmọ rẹ̀,
ọmọ Serahiah, ọmọ Ussi, ọmọ Bukki,
nínú àwọn ọmọ Pahati-Moabu: Elihoenai ọmọ Serahiah àti àwọn igba ọkùnrin pẹ̀lú rẹ̀;