Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Zaphnath-Paaneah: A name given to Joseph by Pharaoh.

1 ẹsẹ · 1 abala

Àwọn ẹsẹ nípa A name given to Joseph by Pharaoh.

  1. Farao sì sọ Josẹfu ní orúkọ yìí Safenati-Panea (èyí tí ó túmọ̀ sí ẹni tí ó ni agbára ikú àti ìyè ní ìkáwọ́ bí òrìṣà). Ó sì fun un ní Asenati ọmọ Potifẹra, alábojútó òrìṣà Oni, gẹ́gẹ́ bí aya. Josẹfu sì rin gbogbo ilẹ̀ Ejibiti já.