Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Wonderful: A name of the Messiah.

2 ẹsẹ · 1 abala

Àwọn ẹsẹ nípa A name of the Messiah.

  1. Ṣùgbọ́n angẹli Olúwa náà dáhùn pé, “Èéṣe tí ìwọ ń béèrè orúkọ mi? Ìyanu ni, ó kọjá ìmọ̀.”

  2. Nítorí a bí ọmọ kan fún wa, a fi ọmọkùnrin kan fún wa, ìjọba yóò sì wà ní èjìká rẹ̀. A ó sì máa pè é ní Ìyanu Olùdámọ̀ràn, Ọlọ́run Alágbára, Baba ayérayé, Ọmọ ọba aládé Àlàáfíà.