Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Comforter, the Holy Spirit: Imparts the love of God 3 ẹsẹ · 16 abala Gbogbo 3 Imparts the love of God 3 Abides for ever with saints · By Christ · By the Father · Communicates joy to saints · Dwells with, and in saints · Edifies the Church · Imparts hope · Is known by saints · Proceeds from the Father · Sent by Christ from the Father · Sent in the name of Christ · Teaches saints · Testifies of Christ · The world cannot receive · Through Christ's intercession · Fi gbogbo 17 hàn Àwọn ẹsẹ nípa Imparts the love of God Romu 5:3Kì í sì ṣe bẹ́ẹ̀ nìkan, ṣùgbọ́n àwa tún ń ṣògo nínú ìjìyà pẹ̀lú, bí a ti mọ̀ pé ìjìyà ń ṣiṣẹ́ sùúrù;Romu 5:4àti pé sùúrù ń ṣiṣẹ́ ìwà rere; àti pé ìwà rere ń ṣiṣẹ́ ìrètí.Romu 5:5Ìrètí kì í sì í dójúti ni nítorí a ti dá ìfẹ́ Ọlọ́run sí wa lọ́kàn láti ọwọ́ Ẹ̀mí Mímọ́ tí a fi fún wa.