Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Tel-Abib
Àwọn ẹsẹ Bíbélì pàtàkì
Nígbà náà ni mo lọ sí etí odò Kebari níbi tí àwọn ìgbèkùn ń gbé ni Teli-Abibu. Níbẹ̀ níbi tí wọ́n ń gbé, mo jókòó láàrín wọn pẹ̀lú ìyanu, fún ọjọ́ méje.