Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Teachers: Elisha, head of, at Gilgal

1 ẹsẹ · 2 abala

Wá "Teachers"

Àwọn ẹsẹ nípa Elisha, head of, at Gilgal

  1. Eliṣa padà sí Gilgali ìyàn sì wà ní ilẹ̀ náà. Nígbà tí àwọn ọmọ wòlíì ṣe ìpàdé pẹ̀lú rẹ̀, ó sì wí fún ìránṣẹ́ rẹ̀ pé, “Gbé ìkòkò ńlá ka iná kí o sì se ọbẹ̀ aláta díẹ̀ fún àwọn ọkùnrin yìí.”