Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Shield: Different kinds of, designated as buckler, shield, target

2 ẹsẹ · 5 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Different kinds of, designated as buckler, shield, target

  1. Di asà àti àpáta mú, kí o sì dìde fún ìrànlọ́wọ́ mi!

  2. Èmi yóò yí ọ kiri, èmi yóò sì fi ìwọ̀ kọ́ ọ ní ẹnu, èmi yóò sì fà ọ́ jáde pẹ̀lú gbogbo ọmọ-ogun rẹ, àwọn ẹṣin àti àwọn agẹṣinjagun nínú ìhámọ́ra, àti ìpéjọ ńlá pẹ̀lú asà ogun ńlá àti kéékèèké, gbogbo wọn ń fi idà wọn.