Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Shelomith: 1. Mother of a blasphemer
Àwọn ẹsẹ nípa 1. Mother of a blasphemer
Ọmọkùnrin arábìnrin Israẹli náà sọ̀rọ̀-òdì sí orúkọ Olúwa pẹ̀lú èpè, wọ́n sì mú un tọ Mose wá. (Orúkọ ìyá rẹ̀ ní Ṣelomiti, ọmọbìnrin Debiri, ti ẹ̀yà Dani.)